Odu Eji Ogbe is one of the most powerful Odu in Ifa divination, offering deep spiritual insights and guidance. This article explores its translation, meaning, associated taboos, and the sacrifices required to unlock its blessings.
Ifa Divination for The Father of Ajero Manje Le
Ifa ni oun pe ire gbogbo fun eni ti odu yii jade fun, Ifa ni ki eleyin rubo ki aye le ba rorun fun, ko fi igbin bo ifa lopolopo. Egbo bi Ifa ti wi:
Bi ojo bakanrin
Orun a ro woo
Adifa fun baba ajero manje le
Igba ti momi oju sogbere ire gbogbo
Ebo won ni o se
O gbebo nibe orubo
Nje, kini aye igbin se
Ero woo salaye igbin
Igbin ase erowo
Ebo: Ifa ni Ki eni na fi Igbin Mejo, Akuko Adie kan, Epo, Eko ati Obi fi rubo.
English Translation
Ifa says it is calling forth all blessings for the person for whom this Odu has appeared. Ifa says this individual should offer a sacrifice so that life can become easier for them, and they should offer many snails to appease Ifa. Here is how Ifa has spoken:
As the day passes gently
The sun shines brilliantly
This was the Ifa declaration for the father of ajero manje le
At the time when tears flowed in abundance for all blessings
He was advised to offer a sacrifice
He complied and offered the sacrifice
Now, what defines the life of a snail?
The life of a snail is one of effortless ease.
The snail exemplifies a life of tranquility and prosperity.
Sacrifice: Ifa says the person should offer eight snails, one rooster, palm oil, cornmeal (eko), and kola nuts as a sacrifice.
Ifa Divination for: Olokira
Ifa ni ki eniti odu yi jade fun rubo komon ba mon se owo aseti, won ni ebo ni kose. Egbo bi Ifa ti wi:
Abede awo olokira
Adifafun olokira
Ti n fi ojojumo sowo aseti
Won ni korubo
Ko mon ba maa sowo ase ti
O osi gbebo nibe orubo
Nje abede ode
Awo olokira
Orunmila mon je ki olokira o se aseti
Ebo: Ki Eleyi fi Akuko Adire Meji, Eku, Eja ati Abodie kan rubo. Ki o le ma bawon se aseti mon.
English Translation
Ifa says this person must offer a sacrifice so they do not face the habit of leaving tasks uncompleted, and instead be able to complete their work successfully. They must offer the sacrifice that will bring blessings.
Here is what Ifa says:
Abede, the priest of Olokira,
Divined for Olokira,
Who had been doing things without success. He was instructed
To offer a sacrifice
So that he would not face the habit of leaving tasks uncompleted
And he complied.
Thus, Abede has arrived,
The priest of Olokira.
Orunmila, do not let Olokira face the habit of leaving tasks uncompleted.
Sacrifice: Let this person offer two roosters, one hen, a rat, fish, and one goat as a sacrifice, so that they will not always leave work unfinished or fail to complete tasks.
Ifa Divination for Orunmila
Ifa pe ire isegun fun eniti odu yi jade fun, Ifa ni ebo ni ko se pe awon kan gbogun ti. Won ni ki enina rubo kole ba segun.
Egbo bi Ifa tiwi:
Sigindin lepo
Sigindin niyo
Singindin ni kolo kolo adi
Adifa fun orunmila
Baba lole gbe aye tuntun niyawo
Ebo ni won ni kose
O gbebo ni be o rubo
Ope asinla lo gbaye tutu niyawo
Aye ifa tutu o joyin lo
E wa bani ni jebutu aya
Ebo: Ifa ni ki eni na fi Eran oruko kan, Epo, Eko ati Obi rubo.
English Translation
Ifa calls forth blessings of victory for the person for whom this Odu has appeared. Ifa says they must offer a sacrifice so that they can overcome obstacles.
Here is how Ifa has spoken:
Singindin is palm oil
Singindin is salt
Singindin is the kolo kolo adi
This was the divination for Orunmila
Who was about to marry a peaceful world as his wife
He was instructed to offer a sacrifice
And he complied
It was with Ope Asinla that he married a peaceful world
The life of Ifa was peaceful, sweeter than honey
Come and join me in the sweetness of marriage.
Sacrifice: Ifa says this person should offer one he-goat, palm oil, cornmeal (eko), and kola nuts as a sacrifice.
Ifa Divination for Kukunduku
Ifa pe ire aseyori, isegun ati oye fun eleyii, ifa ni ebo ni
ko ru, yoo ni isegun. Egbi bi Ifa ti wi:
Bi e gbemi n gbegbe
Bi e ru mi ruuru
Emi ko sai deni
Emi ko sai deniyan
Adifafun kukunduku
Ti o jola lawujo isu oko
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
A mu kukunduku joloja
Gbogbo isu oko
E posese wa e wa sin
Gbogbo isu oko
Ebo: Ki eniti odu yi jade fun fi Eran oruko kan, Epo, Eko ati obi rubo.
English Translation
Ifa calls forth blessings of success, victory, and honor for this person. Ifa says they must offer a sacrifice, and they will achieve victory.
Here is how Ifa has spoken:
If you carry me with you
Or place me on your neck
I will never stop being blessed
I will never stop being successful
This was the Ifa divination for Kukunduku, Yam
Which has the intention to become a leader among the yams
It was advised to offer a sacrifice
And It complied
Therefore, we have chosen Kukunduku as the leader of the yams
All the yams come
To worship the great yam.
Sacrifice: The person for whom this Odu has appeared should offer one he-goat, palm oil, cornmeal (eko), and kola nuts as a sacrifice.
Yoruba Science: AWURE
Ao toju Awo ekun ao toju edun ara ao toju osun ao toju ose. ao wa gun gbogbo re mo ose eni na yio ma fi we laro laro.
English: One will obtain the tiger's skin with thunderstone (Edun Ara), Osun (white powder), and black soap. It will be ground into the black soap, and the person will bathe with it every morning.
Yoruba Science: ISEGUN
Ao toju ewe onire kinkin pelu iyere ao fi se igbin merin lepo ni yo, ao wa se adura si ao je.
English: One will obtain Onire Kinkin herbs with Iyere and use them to cook four snails with palm oil and salt. They should say their prayer before eating it all.